Sáàmù 39:12 BMY

12 “Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa,kí o sì fetí sí igbe mi;kí o má ṣe di etí Rẹ sí ẹkún minítorí àlejò ni èmi lọ́dọ̀ Rẹàti àtìpó, bí gbogbo àwọn baba mi ti rí.

Ka pipe ipin Sáàmù 39

Wo Sáàmù 39:12 ni o tọ