8 Èmi yóò dùbúlẹ̀, èmi ó sì sùn ní àlàáfíà,nítorí ìwọ nìkan, Olúwa, ni omú mi gbé láìléwu.
Ka pipe ipin Sáàmù 4
Wo Sáàmù 4:8 ni o tọ