Sáàmù 42:5 BMY

5 Èéṣe tí o fi n rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mi?Èéṣe tí ara Rẹ kò fi lélẹ̀ nínú mi?Ìwọ ṣe ìrètí ni ti Ọlọ́run,nítorí èmi yóò sáà máa yìn ín.

Ka pipe ipin Sáàmù 42

Wo Sáàmù 42:5 ni o tọ