Sáàmù 42:9 BMY

9 Èmi wí fún Ọlọ́run àpátà mi,“Èéṣe tí ìwọ fi gbàgbé mi?Èéṣe tí èmi o fi máa rìn nínú ìbànújẹ́,nítorí ìnilára ọ̀ta?”

Ka pipe ipin Sáàmù 42

Wo Sáàmù 42:9 ni o tọ