Sáàmù 49:14 BMY

14 Gẹ́gẹ́ bí àgùntàn ni a tẹ́ wọn sínú isà òkúikú yóò jẹun lórí wọn;ẹni tí ó dúró ṣinṣin ní yóòjọba lórí wọn ní òwúrọ̀;Ẹwà wọn yóò díbàjẹ́isà òkú ni ibùgbé ẹwà wọn.

Ka pipe ipin Sáàmù 49

Wo Sáàmù 49:14 ni o tọ