Sáàmù 5:3 BMY

3 Ní òwúrọ̀, Olúwa, ìwọ yóò gbọ́ ohùn mi;ní òwúrọ̀ èmi yóò gbé ẹ̀bẹ̀ mi sí iwájú Rẹ̀èmi yóò sì dúró ní ìrètí.

Ka pipe ipin Sáàmù 5

Wo Sáàmù 5:3 ni o tọ