Sáàmù 50:21 BMY

21 Àwọn nǹkan wọ̀nyí ni ìwọ ti ṣe, mo sì dákẹ́;ìwọ rò pé mo jẹ́ irú kan náà bí ìrẹ,ṣùgbọ́n èmi yóò bá ọ wíèmi yóò sì fi ẹ̀sùn kàn ọ́ ní ojú ara Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 50

Wo Sáàmù 50:21 ni o tọ