Sáàmù 50:3 BMY

3 Ọlọ́run ń bọ̀ bẹ́ẹ̀ ni kì yóò dákẹ́,iná yóò máa jó níwájú Rẹ̀,àti ní àyíká Rẹ̀ ni ẹ̀fúfù líle yóò ti máa jà ká.

Ka pipe ipin Sáàmù 50

Wo Sáàmù 50:3 ni o tọ