7 Èyi ni ọkùnrin náà ti kò fi Ọlọ́run ṣe agbára Rẹ̀,bí kò ṣe ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọrọ̀ Rẹ̀ ni ó gbẹ́kẹ̀léó sì mu ara Rẹ̀ le nínú ìwà búburú Rẹ̀.
Ka pipe ipin Sáàmù 52
Wo Sáàmù 52:7 ni o tọ