Sáàmù 53:6 BMY

6 Ìgbàlà Ísírẹ́lì ìbá jáde wá láti Síónì!Nígbà tí Ọlọ́run bá mú ohun ìní àwọn ènìyàn Rẹ̀ padà,jẹ́ kí Jákọ́bù yọ̀ kí inú Ísírẹ́lì sì máa dùn!

Ka pipe ipin Sáàmù 53

Wo Sáàmù 53:6 ni o tọ