Sáàmù 59:13 BMY

13 Pa wọn run nínú ìbínú,run wọ́n di ìgbà tí wọ́n kò ní sí mọ́.Nígbà náà ní yóò di mímọ̀ dé òpin ayépé Ọlọ́run jọba lórí Jákọ́bù. Sela

Ka pipe ipin Sáàmù 59

Wo Sáàmù 59:13 ni o tọ