16 Ṣùgbọ́n èmi ó kọrin agbára Rẹ,ń ó kọrin ìfẹ́ Rẹ ní òwúrọ̀;nítorí ìwọ ni ààbò mi,ibi ìsádì mi ní ìgbà ìpọ́njú.
Ka pipe ipin Sáàmù 59
Wo Sáàmù 59:16 ni o tọ