Sáàmù 59:9 BMY

9 Ìwọ agbára mi, èmi ó máa kọrin ìyìn sí ọ;nítorí ìwọ Ọlọ́run ni ààbò mi,

Ka pipe ipin Sáàmù 59

Wo Sáàmù 59:9 ni o tọ