Sáàmù 62:7 BMY

7 Ìgbàlà mi àti ògo mí dúró nínú Ọlọ́run;Òun ní àpáta ńlá mi, àti ààbò mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 62

Wo Sáàmù 62:7 ni o tọ