Sáàmù 68:27 BMY

27 Níbẹ̀ ní ẹ̀yà kékeré Bẹ́ńjámínì wà, tí o ń darí wọn,níbẹ̀ ni àwọn ọmọ aládé Júdà,níbẹ̀ ni àwọn ọmọ aládé Sébúlúnì àti tí Náfútàlì.

Ka pipe ipin Sáàmù 68

Wo Sáàmù 68:27 ni o tọ