Sáàmù 69:14 BMY

14 Gbá mí kúrò nínú ẹrẹ̀,Má ṣe jẹ́ kí ń rí;gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí o korìíra mi,kúrò nínú ibú omi.

Ka pipe ipin Sáàmù 69

Wo Sáàmù 69:14 ni o tọ