Sáàmù 69:4 BMY

4 Àwọn tí ó kórìíra mi láìnídìíwọn ju irun orí mi; lọpúpọ̀ ni àwọn ọ̀tá mi láìnídìí,àwọn tí ń wá láti pa mí runA fi ipá mú miláti san ohun tí èmi kò jí.

Ka pipe ipin Sáàmù 69

Wo Sáàmù 69:4 ni o tọ