Sáàmù 7:9 BMY

9 Ọlọ́run Olódodo,Ẹni tí ó ń wo inú àti ọkàn,tí ó ń mú òpin sí ìwà ipá ẹni búburútí ó sì ń pa àwọn olódodo mọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 7

Wo Sáàmù 7:9 ni o tọ