Sáàmù 71:18 BMY

18 Pẹ̀lúpẹ̀lú, nígbà tí ẹnu di arúgbó tán tí mo sì hewú,Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀, Ọlọ́runtítí tí èmi o fi ipá re han ìran yìíàti agbára Rẹ fún gbogbo àwọn aráẹ̀yìn, sọ ti agbára sí ìran tí ń bọ̀agbára Rẹ̀ fún àwọn tí yóò wá.

Ka pipe ipin Sáàmù 71

Wo Sáàmù 71:18 ni o tọ