Sáàmù 85:8 BMY

8 Èmi ó gbọ́ ohun tí Olúwa Ọlọ́run yóò wí;ó ṣèlérí àlàáfíà fún àwọn ènìyàn Rẹ̀, àní ẹni mímọ́ Rẹ̀:Ṣùgbọ́n má ṣe jẹ́ kí wọn padà sí àìmòye.

Ka pipe ipin Sáàmù 85

Wo Sáàmù 85:8 ni o tọ