Sáàmù 86:5 BMY

5 Ìwọ ń daríjì, ìwọ sì dára, Olúwa,ìwọ sì ṣàánú fún gbogbo àwọn ti ń ké pè ọ́,

Ka pipe ipin Sáàmù 86

Wo Sáàmù 86:5 ni o tọ