Sáàmù 9:11 BMY

11 Kọ orin ìyìn sí Olúwa, ti o ń jọba ní Síónì;kéde láàrin àwọn orílẹ̀ èdè ohun tí o ṣe.

Ka pipe ipin Sáàmù 9

Wo Sáàmù 9:11 ni o tọ