Sáàmù 91:2 BMY

2 Èmi yóò sọ nípa ti Olúwa pé,“Òun ní ààbò àti odi mi,Ọlọ́run mi, ẹni tí èmi gbẹ́kẹ̀lé”.

Ka pipe ipin Sáàmù 91

Wo Sáàmù 91:2 ni o tọ