Sáàmù 91:4 BMY

4 Òun yóò fi ìyẹ́ Rẹ̀ bò mí,àti ni abẹ́ ìyẹ́ Rẹ̀ ni èmi yóò ti rí ààbò;òtítọ́ Rẹ̀ ni yóò ṣe ààbò àti odi mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 91

Wo Sáàmù 91:4 ni o tọ