Sáàmù 93:3 BMY

3 A ti gbé òkun sókè, Olúwa,òkun ti gbé ohùn wọn sókè;òkun ti gbé rírú omi wọn sókè.

Ka pipe ipin Sáàmù 93

Wo Sáàmù 93:3 ni o tọ