9 Ẹ jẹ́ kí wọn kọrin níwájú OlúwaNítorí tí yóò wá ṣè dájọ́ ayébẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè nínú òdodoàti àwọn ènìyàn ní àìṣègbè pẹ̀lú.
Ka pipe ipin Sáàmù 98
Wo Sáàmù 98:9 ni o tọ