4 Olúwa ń bẹ nínú tẹ́ḿpìlì mímọ́ Rẹ̀; Olúwa ń bẹ lórí ìtẹ́ Rẹ̀ ní ọ̀run.Ó ń wo àwọn ọmọ ènìyàn;ojú Rẹ̀ ń yẹ̀ wọ́n wò.
Ka pipe ipin Sáàmù 11
Wo Sáàmù 11:4 ni o tọ