Sáàmù 126:6 BMY

6 Ẹni tí ń fi ẹkún rìn lọ,tí ó sì gbé irúgbìn lọ́wọ́,lóòtọ́, yóò fi ayọ̀ padà wá,yóò sì ru ìtí Rẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 126

Wo Sáàmù 126:6 ni o tọ