Sáàmù 32:6 BMY

6 Nítorí náà jẹ́ kí gbogbo àwọn olódodo máa gbà àdúrà sí ọní ìgbà tí a le ri ọ;nitòótọ́ nígbà tí ìṣàn omi ńlá bá ru sókè,wọn kì yóò le dé ọ̀dọ̀ Rẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 32

Wo Sáàmù 32:6 ni o tọ