Sáàmù 34:10 BMY

10 Àwọn ọmọ kìnnìún a máa ṣe aláìní ebi a sì máa pa wọ́n;ṣùgbọ́n àwọn tí ó wá Olúwa kì yóò ṣe aláìní ohun tí ó dára.

Ka pipe ipin Sáàmù 34

Wo Sáàmù 34:10 ni o tọ