Sáàmù 34:11 BMY

11 Wá, ẹ̀yin ọmọ mi, fi etí sí mi;èmi yóò kọ́ ọ yín ní ẹ̀rù Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 34

Wo Sáàmù 34:11 ni o tọ