Sáàmù 4:1 BMY

1 Dá mi lóhùn nígbà tí mo bá pè ọ́,iwọ Ọlọ́run òdodo mi,Fún mi ní ìdánídè nínú ìpọ́njú mi;ṣàánú fún mi, kí o sì gbọ́ àdúrà mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 4

Wo Sáàmù 4:1 ni o tọ