Sáàmù 4:2 BMY

2 Báwo ni yóò ṣe pẹ́ tó, ẹyin ọmọ ènìyàn, tí ẹ ó ṣe sọ ògo mi di ìtìjú?Báwo ni yóò ṣe pẹ́ tó,tí ẹ̀yin yóò ṣe fẹ́ràn ìtànjẹ́ àti tí ẹ̀yin yóò fi máa wá Ọlọ́run èké?

Ka pipe ipin Sáàmù 4

Wo Sáàmù 4:2 ni o tọ