Sáàmù 4:3 BMY

3 Ṣùgbọ́n kí ẹ mọ̀ pé, Olúwa ti ya ẹni olódodo ṣọ́tọ̀ fún ara Rẹ̀; Olúwa yóò gbọ́ nígbà tí mo bá pè é.

Ka pipe ipin Sáàmù 4

Wo Sáàmù 4:3 ni o tọ