Sáàmù 44:3 BMY

3 Kì í ṣe nípa idà wọn ni wọn gba ilẹ̀ náà,bẹ́ẹ̀ ni kì í se apá wọn ní ó gbà wọ́n bí kò se;ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ àti, apá Rẹ̀;àti ìmọ́lẹ̀ ojú Rẹ̀, nítorí ìwọ fẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Sáàmù 44

Wo Sáàmù 44:3 ni o tọ