Sáàmù 52:9 BMY

9 Èmi yóò yìn ọ títí fún ohun tí ó ti ṣe;èmí ní ìrètí nínú orúkọ Rẹ, nítorí orúkọ Rẹ dára.Èmi yóò yìn ọ́ níwájú àwọn ènìyàn mímọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 52

Wo Sáàmù 52:9 ni o tọ