Sáàmù 53:1 BMY

1 Asiwèrè wí ní ọkàn Rẹ̀ pé:“Ọlọ́run kò sí.”Wọ́n bàjẹ́, gbogbo ọ̀nà wọn sì burú;kò sì sí ẹnìkan tí ń ṣe rere.

Ka pipe ipin Sáàmù 53

Wo Sáàmù 53:1 ni o tọ