Sáàmù 59:4 BMY

4 Èmí kò ṣe àìṣedédé kan, ṣíbẹ̀ wọ́n sáré,wọ́n ṣetán láti kọlù mi. Dìde fún ìrànlọ́wọ́ mi,kí o sì wo àìlera mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 59

Wo Sáàmù 59:4 ni o tọ