5 Olúwa Ọlọ́run alágbára, Ọlọ́run Ísírẹ́lì,dìde fún ara Rẹ kí o sì bá àwọn orílẹ̀ èdè wí;Má ṣe ṣàánú fún àwọn olùrékọjá búburú nì. Sela
Ka pipe ipin Sáàmù 59
Wo Sáàmù 59:5 ni o tọ